Yoruba Greetings, (Middle) Names In Yoruba Language With Titles Of Obas (Kings) Bi A Se NKi Awon Onirunru Eniyan Ni Ile Yoruba Ati Oruko-Oriki Pelu Apele Awon Oba




Yoruba Greetings To Say To Various People And (Middle)
Names In Yoruba Language (As In Yorubaland)
With Titles Of Obas (Kings) By Aduni Razak Musulumi (Muslim) – Mo salama o / (As)Salam (a)lekum o Oko-Iyawo Titun (Groom) – Ehin iyawo ko ni m’eni o. Iyawo Titun (Bride) – Ibujoko ayo o. Alagbede (Smith) – Aroye Onise Oluwa / Alufaa (Cleric / Quranic teacher) – E kun ise Oluhun Agbe (Famer) – Arokobodunde Akope (Anyone who has to climb) – Igba a ro o Olujosin (Worshipper / One on the way to or from mosque/prayer ) – Olohun a gba Onidiri (Hairdresser) – Oju gbooro / E kun ewa Eniti o Ti Ajo De (Arriver / New comer ) – E kun Abo Eniti o Ti A De Ba Ni’le (Receiver / to whom one comes) – E kun ile Olurin / Olukoja (Passer-by) – Aarewa o Onirin-Ajo (Traveller) – Arinye o, oko a re fo o Eni Oku Omode Ku Fun (Bereaved of young person) – E kun iroju, Alapa dupe ni Olohun Eni Oku Agbalagba Ku Fun (Bereaved of old person) – E kun ilede, Alapa dupe ni Olohun Onisowo (General trader) – Aje a wo gba o Onilu (Drummer) – Aluye Akeko (Student / Learner) – Akaye Oluko (Teacher / Trainer) – Akoye Alaro (Dyer or artist) – Aredu / Arepa Eni Oku Alaboyun Ku Fun T’omotomo (Bereaved of pregnant person with child(ren)) – E kun iroju, Alapa dupe ni Olohun Eni Oku Alaboyun Ku Fun T’omoye (Bereaved of pregnant person with Child(ren) surviving ) – E kun iroju, Omo asesan, Alapa dupe ni Olohun Eni Oku Omo Oyun Ku Fun T’iyaye (Bereaved of Pregnant Child(ren) With Mother Surviving ) – Omi L’odanu, Agbe K’ofo, Alapa Dupe Ni Olohun Olode (Hunter) – Arinpa t’ayotayo Awako (Driver) – Awaye o, Oko a re fo o Alaawe (Who’s fasting) – E kun oongbe, Olohun a gba Eniti-O-Gbawe (Who’s completed fast) – Ki Olohun k’o gba Osise Ijoba (Civil Servant ) – Oko oba ada oba ko ni sa nyin l'ese Ara Ati Ebi Oloyun (Friends and relative of pregnant woman) – A gb’ohun iya a gb’ohun omo o / Afon a gbo k’o to wo Oloyun (Pregnant woman) – Asokale anfaani o / Afon a gbo ki o to wo :: Oruko Amutorunwa Gege bi Asa :: Names Given
To Describe Births According To Yoruba Traditions Olugbodi- Omo ti a bi, ti oni Ika owo mefa Ajayi – Omo ti a bi, ti o da oju bole Ojo – Omo ti a bi ti o gbe ibi ko run Oke – Omo ti o wa ninu apo Ige – Omo ti omu ese waye Salako – Omo ti a bi, ti nkan bo lo’ju Ilori – Omo ti a bi nigba ti iya re se nkan osu Dada – Omo ti irun ori re lopo tabi to ta koko Oke – Omo ti ko fe ki a ro oun ni ounje ni idu bule Babarimisa – Omo ti a bi ni kete ti baba re ku Aina – Omobirin ti o gbe ibi korun Tayewo – Omo ti o si waju de nigba ti aba bi ibeji Kehinde – Omo ti o kehinde nigbati ba bi ibeji Idowu – Omo ti a bi tele ibeji Alaba – Omo ti a bi tele Idowu Ajasa – Omo ti a bi ti ikun re nikan wa ninu apo Amusan – Omo okunrin ti a bi, ti ori re nikan wa ninu apo Erinle – Omo ti a bi ti ogbe ibi ko orun owo tabi ese tabi ibadi Ato – Omobinrin ti a bi ti ori re nikan wa ninu apo :: Apeje Awon Oba Ni Ile Yoruba - Laiko Je Ti Tele-n-
tele Kan San an :: Titles Of Oba Yoruba (Yoruba
Kings) - Not In Particular Order Alaafin ti Oyo Ooni ti Ile Ife Alaake ti Egba Ataoja ti Osogbo Orangun ti Ila Awujale ti Ijebu Ode Owa Obokun ti Ijesha Alaketu ti Ketu Alaake ti Egba Emir ti Ilorin Oba ti Eko Olubadan ti Ibadan Soun ti Ogbomoso Aseyin ti Iseyin Olufi ti Gbongan Orimolusi ti Ijebu Igbo Olowo ti Owo Oloru ti Oru Ajero ti Ijero Deji ti Akure Onitire ti Itire Jagun ti Ile Oluji Olota ti Otta Alapomu ti Apomu Ayangburin ti Ikorodu Alaye ti Efon Alaye Onidere ti Idere Ewi ti Ado Ekiti Osemawe ti Ondo Menuteyi ti Badagry Osolo ti Isolo Olofa ti Offa Timi ti Ede Akarigbo ti Remo Elekole ti Ikole Ekiti Abodi ti Ikale Akire ti Ikire Olobaagun ti Obaagun Onigbeti ti Igbeti Sabiganna ti Iganna Ajoriiwin ti Irewo Elende ti Eko- nde Arowaja ti Iwaraja Oluepe ti Epe Eko Oloja ti Epe Ijebu Onjo ti Okeho Elero ti Ilero Oloje ti Oje-owode Olokuku ti Okuku Owa ti Otan Ayegbaju Olu ti Agege Olufon ti Ifon Osun Elerin ti Erin Osun Aragbiji ti Iragbiji Onisemi ti Isemi Olokaka ti Okaka Owa ti Igbajo Onipokia ti Ipokia Aree ti Ire Obalufon ti Sepeteri Elerin ti Erin Ile Olu ti Ikeja Onidimu ti Idimu Olobu ti Ilobu Olu ti Ile Ogbo Olugunwa ti Oke Amu Onilua ti Ilua Alamodu ti Agoamodu Olowu ti Owu Agura ti Gbagura Oluwo ti Iwo Aro ti Oro Olosu ti Osu Obara ti Kabba Ogiyan ti Ejigbo Eleyinpo ti Ipapo Apetu ti Ipetumodu Origbin ti Oke Igbin Iba ti Kisi Onitede ti Tede Akirun ti Ikirun Onilala ti Lanlate Alaye ti Ayetoro Yewa Ogoga ti Ikere Ekiti Oloyan ti Oyan Osile ti Oke Ona Ebumowe ti Ago Iwoye Alaye ti Ode Remo Onigbajo ti Igbajo Ogunsuada ti Modakeke Olomu ti Omupo Edemo ti Ishara Onikoyi ti Ikoyi Olu ti Igbo Ora Asigangan ti Igangan Asawo ti Ayele Eleruwa ti Eruwa Olu ti Ilaro Alawo ti Awo Alara ti Aramoko Posted By Ifiranse Eleyi Je Friday, February 04 @ 06:45:38 PST Lati Owo MediaYorubaTeam Awon Itona Ti O Bayi Mu · Ekunrere Nipa Atoka Feyikogbon - Ninu Oye Esin Ati Imo · Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Atoka Feyikogbon - Ninu Oye Esin Ati Imo: Yoruba Greetings, (Middle) Names In Yoruba Language With Titles Of Obas (Kings)
Share on Google Plus

About 9jalead

0 comments:

Post a Comment